Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òyèkù Ósà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for caution and careful planning to avoid unforeseen dangers.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oyeku-osa
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyeku teku asa O yan kete kete Adifafun popondo Eni ti o gbori ote re dade Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E ba ni larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo, pe aarin ota ni eleyii wa, sugbon aarin ota naa ni yoo ti la.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji Eyele meji Abo adie meji Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oyeku teku asa oyan kete kete Adifafun abe sekete ti n be laarin ota Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, omode kii gboju gboju Ko maa foribale fabe Abe o maa ti dorisa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni awon ota eleyii ju eleyii lo paa paa won ni agbara juu lo, pe ki eleyii o rubo gbogbo won ni n won o wa maa foribale bale fun un

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abe fele meta Akuko adire meta Epo Eko Agbado Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyeku sale babe Eruku so gbagba nin poro oko Adifafun Erigi alo Tii segbon ope agbe Igba ti n fomi oju sogbere aje suru suru Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Aje wa je de tuturu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire aje n bo feleyii lati okere, oore naa sipo gidi gidi, pe ki eleyii o rubo koore naa o le too lowo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Owo Epo Eko Agbado
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Eminrin gesin bee ni koni kese Amukuru gesin bee ni ko si bata Ire toni kese toni bata beeni o rese gori esin Adifafun Oyeku it n rele osa lee sawo Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, igba ti oyeku sawo dele osa Eesin ni ao maa gun sawo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ibi kan ni eleyii fee lo yii, pe korubo pe yoo ri ire aje mubo nibe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Iyan ati obe egusi pelu eja Oti Obi Abo adie meji Epo Eko Agbado at owo

Videos

Watch Òyèkù Ósà teachings on our channel.

Explore Ifa

Òyèkù Ósà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyekú Méjì, Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òyèkù Ósà Odu.