Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òyèkù Òtùrùpòn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
A short interpretation of Òyèkù Òtùrùpòn
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oyeku-oturupon
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyeku baturupon Ire gbogbo womun lapo odiwomun Lapo ire gbogbo Adifafun bata ti n be laarin ota Ebo ni won ni ko se O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E wa bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pere isegun ota fun eleyii, pe oore eleyii kan n be ti won jo maa n se wole wode ko sora fun ota gidi nin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ekuru funfun Obi Akuko adire meji Epo Eko Agbado ati owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Wondagba nile olufon Won lulu kan gidigidi lakodijesa Adifafun Olodumare Omo ateniola fori sapeji Igba ti n be laarin ota Ebo ni won ni kose O gbebo nibe o rubo Nje, oun to ba wufa nin eje ko se Ara to ba weledua ni n da To ba ta dudu ata funfun Ata ayinrin afi pelu e

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyii o rubo, pe awon ota kan ree ti won fowo bo irawo eleyii ko rubo ko lee baa segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aso dudu Aso funfun Aso ayinrin Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyeku baturupon aringindinwin Adifafun Orunmila Baba n sunkun alairejemun Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Aje wa jede tuturu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire aje n bo feleyii sugbon ko fi ewure bofa kaje eleyii o le baa de

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewure Obi Oti Akuko adire kan Abo adire kan Epo Eko Agbado ati owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Olukowko jikonko Adifafun Orunmila Nijo gbogbo ire nlo, okankan o yale Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ko e pe o Ko ee jinna Aje wa jede tururu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire n koja eleyii sugbon ire naa ko te eleyii lowo, ko rubo, kore naa o lee too lowo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Elede kan Obi Oti Akuko adire kan Eyele kan Abo adie kan Epo Eko Agbado ati owo

Videos

Watch Òyèkù Òtùrùpòn teachings on our channel.

Explore Ifa

Òyèkù Òtùrùpòn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyekú Méjì, Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òyèkù Òtùrùpòn Odu.