Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Oyeku Ogbe

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
Òyèkù Ogbè Excerpt
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/oyeku-ogbe
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Opa gila awo ni
Opa gila awo ni n se
Adifafun agbaagba mefa tinbakin sota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore isegun fun eleyii, pe awon agbaagba mefa kan wa ti won n ba eleyii sota, pe ki eleyii o rubo, ko si bo esu ko lee ba a segun won.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan
Obi meji
Epo
Eko
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oyeku logbe labara
Babalawo awonriwon
Adifafun awonriwon
Ti n be laarin awon ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore isegun fun eleyii, ifa ni eleyii yoo ni ota kan ni egbe ti yoo maa soro fun sugbon ki o so enu re pelu iru eni be, pe yoo segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji
Eja meji
Abo adie kan
Alabahun kan
Akuko adie kan
Epo igo kan
Eko meji
Opolopo owo.
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyeku logbe labara
Kasape kafijaro adifaje
Ti n tikole orun bowale aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore aje fun eleyii, ifa pe eleyii yoo rire gbogbo nibi ijoko re ati lenu ise.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ekuru funfun
Opolopo eyin,
Ogede omini,
Oyin ati
Obi Meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa tiri
Adifafun Orunmila
Aje nje lo ti ko yale wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oju aje n pon eleyii, ifa ni ko lowo lowo, ifa ni ki eleyii o rubo, ko si fi oya bofa, ifa ni aje o ya ile re.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oya kan
Obi meji
Opolopo oti
Epo
Opolopo owo
Eyele

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

1.
Ao bu yangi esu die, ewe segun sete, ewe alupaida, oko ataare kan, ao lo po, ao fi sin gbere igba ati eyokan la ori eni ja

Videos

Watch Oyeku Ogbe teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Iwori, Oyeku Odi, Oyeku Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Ogbe Odu.