Ò
This Odu represents the need for balance and harmony in life.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Wedo Babalawo
Adifafun igbangba
Nigba ti n torun bowa sile aye
Adifafun Awo awo
Igba ti n tode orun bo wa sile aye
Ebo ni won ni ko se
Awo nikan ni n be leyin ti n tubo
Nje, igba nin won pa enin tan kii pawo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eleyii, ifa ni ki eleyii o rubo pe omo iya eleyii kan re e, ota re gidigidi ni, ki eleyii o rubo ko maa je pe yoo fe e paa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igba olomori
Awo olomori
Akuko adie kan
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Owonrin wokun woku
Adifafun oro
Ti n be laarin ota
Ebo ni won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Oro loun sebo owonrin wokun woku
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni keleyii o rubo ko le baa segun nitori ota po fun
eleyii.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko Kan
Obi meji
Oti
Akuko adie kan
Eyele kan
Epo
Eko
agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Owonrin worun wedo
Adifafun Alabahun ajapa
Ti n loko ai lero lodun
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
E wa bani bola peregede
Owonrin wokun wedo
Adifafun Olunlawe
Ti n rode orun bo wa sile aye
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
E bani bola peregede
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eleyii, pe ibikan ni eleyii n lo, pe yoo la bo nibe sugbon kogbo ikilo ti won ba n wi fun un.
Ifa pere ola fun eleyii lati okere, pe korubo ki ire ola naa o le too lowo ni kia kia.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igba olomori
Obe
Epo
Agbdo
Owo
Eyele funfun meji
Obi merindinlogun
Epo
Eko
Agbado
Explore Ifa
Òfún Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òfún Òwónrìn Odu.
