Ò
This Odu signifies the importance of communication and expression.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ofun muntaba fio fio
Tete regun fidiregbe sayo
Adifafun lapande
Omo ari kokoro seleyo bomi mun
Igba ti n momi oju sogbere omo
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Nje eyan toso elede lekuro ounje omo lowafun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere omo fun eni toda
ifayi ki o rubo kole babi omo
kofi aboadie ati eku eja bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu
Eku
Agbeboadie
Eko
Epo
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Moya ni hin moya loun moyamon
Moya ojomo onibi o tete dele
Adifafun aidegbe
Tio figba won yun latode orun wa sile aye Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Nje moyun mobo morire
Esu odara bami segun
Iyara moyun mobo morire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda ifayi
ki elleyi orubo nitori igare ki o
si lobo esu odara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
akuko adie
igbin
alabahun
Agbado
eko
epo
opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
ofun je wujewu awole
ofun dododo awo ode
idogin nidogin awo ode bio pon
adifafun laro ti se omo bibi
inu agboniregun igba ti n momi
oju sogbere ire gbogbo EBO
won ni ose osi gbebo ni be orubo nje aye laoni lawa ro adegbo omi awaro iregbo gbo laoni lawaro adegbo omiro awa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere ffun eni toda ifa
ifa ni oju ire gbogbo nip on
elelyi ifani komo sebi toun
kosi mobo fa leku leja
lobi adie ifa ni odo oun ni oore re wa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
agbado adie
eku
eja
eko
epo
opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ofun muntaba fio fio
Tete gun niya palaka
Awo Idabara
Adifafun olu poriko
Tise omo binrin irada
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe o rubo
Nje eyan to so elede lekuo
Ounje omo lowa fun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda ifayi
ifa ni oju omo pon elelyi kio
rubo kole ba bi omo ko fi eku
eja agbeboadie ko fi bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eku
eja
ekuo
agbebo adie
opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AWURE
aotoju opolopo ewe taba tuntun ao wa lo ti yio kun naa ao wa po mon ose dudu ao wa loda lafinda ti oba lorun darada si ao wa mon fi we larolaro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ogun agbede ao wa lo mejejeji po ao wa fi si gbere meta meta si ori rire ara ao wa fi iyoku fo eko mu
Explore Ifa
Òfún Òtùrùpòn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òfún Òtùrùpòn Odu.
