Ò
This Odu highlights the need for cleansing and renewal.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ororo ni meran
Adifafun Molaika
Eyi ti o paa gbonrin tan
Ti yoo fi itan re ase
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Nje mola iku pagban rintan
O fi tan re ase
Awo rere lororo ti n meran
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda ifayi
ki eleyi orubo ki ire ola ba
to lowo kosi lo bo oogun
ko si mo se ahun komo
se ore fun awon
eyan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Eye le
Igbin
Eko
Epo
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ofun lese lese
Awo ile onilese
Adifafun onile se
O ji, oni oun o marun tise oun
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje, onilese arun kan ojo wo lo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda ifa yi ki elleyi orubo nitori
arun owo ifa ni arun
kan nse eleyi ninu ara
ifa ni arun owo ni koruko
ki arun naa ola balo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Eyele
Agbado
Epo
Eko
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ofun suhin
Babalawo arugbo
Lose fa fun arugbo
Nijo ti arugbo lo soko ganrin
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo ni be orubo
Nje, nijo toro
Nijo kobo
Awo rere ni kole seyi
suhin manla aworere
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi
ko rubo ki osi mon kanju ore
pe ire gbogbo yio wa fun
kio lobo orire pelu eyele
kio sifi akuko adire meji rubo
fesu odara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eyele kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ofun se
Babalawo aje
Lo sefa fun aje
Aje n tode orun bowaye
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe orubo
Nje, aje loniso
Fiso sile awo o
Aje loni so
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa nip e ohun pe ire aje fun
eleyi ki elelyi olobo aje pelu
eye etu meji kio si fi oruko bo esu odara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Eran oruko kan
Epo
Eko
obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe ela ajagun morASE ewe akisan iyere ao wa lo gbogbo re pao ao wa fi se eran okiri ewure merindinlogun je ao wa se adura si ao wa je obe naa.
Explore Ifa
Òfún Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òfún Òsé Odu.
