Ò
This Odu emphasizes the importance of clarity and vision.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Won ni wono mo fan ti olu
Won fan ti olu igba erin si
Won re gbio oni koko bo jo
Won ni won omo fan wo lu
Fan wan fanwolufan igba
Efan si won releju fo fobo
Adifafun orunmila baba nbe
Mnirangun ota ebo won ni o se
Osi gbe bo nibe orubo
Iya alado ewi yan nan mi alaworosasa oyan nanmi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda fayi ifa ni ki elelyi o rubo ifani arin awon ota ni elelyi wa korubo kole ba se gun wo kosi fi iyan bo ifa kiwo oto gun iyanyi won o koko mu isu bi meji sinu abo won owa fi epo pupa si enito dafayi yowa je ni idi odio
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko Adie
Igbin
Alabahun
Eko
Epo
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ekan ni o jeraye run be nile olonje Adifafun olugbon
Agbe omo agbe gba losi
Omo olugbon saki
Igba ti n momi oju sogbere ire
Ebo ni won ni ose
O si gbebo nibe o rubo
Ruru ebo
Eru atuka esu
E wa bani nije butu ire
Ofun pa perengede
Adifafun aha
Tirogun ajee amunye
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Ruru ebo
Eru atuka esu
E wa ba mi laru segun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda
ifayi ika ni oju aje ni pon
eleyi ki o rubo kole ba ni aje
ifa pere fun eni toda ifayi
ifa ni ki elleyi o rubo ko
le ba segun ifa ni ogun po
fun elelyi korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Eye etu
Pepeye
Eko
Epo
Opolopo owo
Akuko adie
Alabahun
Igbin
Eko
Epo
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Te ileke se date onula
Aso igba se daso oko
Adifafun ina oni oun o joye olonroro ate ileke
Se sate onula aso
Igba a sedaso oko
Adifafun Orun oloun o joye olonroro ateleke se date onula aso igba seda So oko
Adifafun Osupa olun ojoye Olonroro Ebo won ni won o se
Osupa ni kan ni n be leyin omo olonroro Amun ina joye obaye je
Orun ode omo olonroro amun orun joye obayeje
Osupa de omo olonroro amun
Osupa loye aye gun
Ofun ka
Ofun ko
Adifafun okokomiyele
Abimo mowase
Igba ti momi oju sogbere omo
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Nje, badie ba se koko
Omo loyekle n sun kun pe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifa ki elleyi o rubo ifa ni ounoere oye fun elelyi ko si mo roro mo awon eniyan
ifa pere fun eni to da fayi ki
eleyi orubo ifa ni oju omo ni
pon elelyi korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
akuko adie
eyele
eye etu
eko
epo
opolopo owo
Agbebo adie
Eku
Eja
Eko
Epo
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ani ki won mo fan ti olu won Fan
Ti olu igba erin si won re gbo
Olu koro koro mojo won ni won o mo fan Wolu fan won fan wolu
Igba efan ya won ree eleju gbogbo fo ayanu ayanu nijoyun omo kan o dueo Adifafun orunmila
ti iku po kankan le irunmola
yi aye EBO won ni o se osi
gbebo nibe orubo
Mee ti bawon yun
Mee tiba won ree
Koro koro ide kimomo bawon
yun bo orisa
Ofun won kaka
Oniwon koko
Adifafun agbaku oni se oba
Inanaja eero
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Ruru ebo
Eru atuka aesu
E wa bani bola ba perengede
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun elelyi ki o rbo iku owowo ifa ni eleyi osun oorun korun osi lala kala kio rubo pe apoere iku ni
ifa pere fun enitoda ifayi
ki elelyi orubo si enu isere ko
lebala ifani tielelyi ba wa
labe enikan tinjisefun kio
rubo kole balanibe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Epo
Eko
Opolopo owo
Ikode
Eye etu
Pepeye
Eyele
Eko
Epo
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao ju ori eye igun toju ori
eye asa ao toju ori eye lekeleke
ao toju efu osu ao wa jo gbogbo re papo ao wa gun papo mon ose dudu ao wa fui owo eyo merindinlogun gun ose naa lori ao wa mon buwe laro laro
AWURE
Ao toju ewe ela ewe akisan ao toju iyere ao wa fi se eyele funfun meta lepo niyo ao w ate iyere osu ni odu ifa ofun ohun ika ao wa se adura si ao wa je obe yi egungun re tobakun ao lobo mon idin esu
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju ewe oraba ao toju ewe
eru ao toju ori aja ao wa jo gbogbo re papo ao wa mon fi pese fun awon iya mi pelu eran akape ati epo pupa ao mon so gbogbo ohun ti aba fe si
Ao toju epo igin winla ao toju ewe aje obala ao toju ewe lorugo ao toju igbin kana o wa gun gbogbo re papo mon ose dudu ao wa mon fiwe
Explore Ifa
Òfún Ósà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òfún Ósà Odu.
