Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Aja nara pati pati
Adifa fun gudu gudu
Tii selegbe dundun
Igba tin be laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Kosi fi obi meji bori omore
Ori omo eleyi nin yio ba segun
Paapaaju lo ibikan leleyin loyi
Korubo kolebaa de
Kiwon oman pa soun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Akuko kan
Ese — Yoruba Verse
Aja nanra pati pati
Adifa feetan ti n se elegbe eyin
Igba tinbe laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Kosifi agbon bori omore
Ati eetan eyin
Nintori ki awon ota
Oman baa man pa omo eleyi
Nintori won ofe keleyi
Oloman laye
Wonfe pa omo re tan
Pata pata nin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
Aja nanra pati pati
Adifafun lewa
Ti n tode orun bo waye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ire aje lopo lopo fun eleyi
Keleyi osi bo eegun
Eegun yio dako owo re wafun
Eleyi yio si kole lodun yi
Nintori lati ode orun leleyi tiyan ri ola Kosinin eegun ti man bo lodo dun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Aofi eko oole obi oti, ati owo bo eegun
Ese — Yoruba Verse
Aja nanra pati pati
Aigun okan agba gudu gudu eeso jogba dundun Adifafun orunmila
Baba ji baba orowo kan a yona
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Orubo nintori oju aye
Npan eleyi eleyi ko lowo lowo
Eleyi saro ye owo
Korubo irere feede tan
Keleyi osiman sooto
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Eekan gudu gudu awo ilu dundun eetan eyin adidi atare kan aojo po ao man fi foko mun aotun fi sin gere meta meta nindeti
Awon oju eegun
Ewe je oojo
Ewe saworo pepe oojo
Alupaide oojo
Ao gun gbogbo re po mose
Ao man fiwe
Explore Ifa
Ofun Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Ofun Ogbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Oyeku, Ofun Iwori, Ofun Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Ogbe Odu.
