Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Baba lawo apa
Lodifa fun apa
Igba tinbe laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Kole baa segun awon otare
Nintori wipe laarin ota
Nin eleyi wa
Keleyi osiman man binun si
Awon omo re man
Nintori ti awon ota oman
Baa ti bi omo mun eleyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
Adifafun orunmila
Baba n be laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa loun oba ekleyi segun
Awon otare
Nintori ota eleyi po
Sugbonifa loun oba segun
Keleyi osi man lo onan oko
Fun ojo meje
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
iwori wo irere irere
Adifafun olu oni fila ododo
Igba tin fomi oju sogbere aje
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Nintori ire ajerenbo
Eleyi kolowo lowo nin otorire
Dafasi korubo
Ajenbofun kosifi
Fila odod kun eboreru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
Irere irere
Adifafun esu odara nin jo tin fomin
Ojusogbere ire gbogbo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
eleyi EBOn in koman se
ninu ile eleyi leleyi o wa
tiwon ofi man munre re wafun
keleyi osi fi akuko die kan
bo esu ati obi meji
ati opo lopo epo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
man oko ataare kan
ao fi sin gbere
igba ati eyo kansi
aarin ori ao man
fi yoku foko mun
Explore Ifa
Ofun Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Ofun Iwori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Iwori Odu.
