Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oyeku Iwori

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Òyèkù Iwòrì Excerpt
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oyeku-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyeku biwori tititi Adifafun ike eyin amu Igba ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo, awon ota kan n da eleyii laamu, won so pe eleyii o ni nisinmi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igba ademu kan Akuko adie kan Eyele kan Epo igo kan Eko meji Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Petenbole okirinkisi Adifafun Olukoso laalu banbi arigbota segun Igba ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo pe laarin ota ni o wa, ota lo yi eleyii ka, sugbon sango ni o ba eleyii segun, ki eleyii o fi okuta mesan kun ebo ru.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Amala gbegiri Orogbo meji Akuko adie kan Oti Opolopo owo Eyele meji Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyeku biwori siyin Oyeku biwori sohun Owatanan ola saarin re Singin singindin Adifafun aje tii somo olokun osin eepe Eyi ti o laa laa tenikan o nin le teni funman

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire aje fun eleyii, ifa ni owo naa yoo po debi wipe eni kan o ni maa bi owo re se poto mo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo ekuru Obi meji Oyin Oti Eyele funfun kan
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Elegbe ni n kegbe awo ode aro Ologba ni n kogba awo odofin Oyeku loluwori lolugbonan Boya oba seere maa itufu a si maa gbedire Adifafun Orunmila Ifa n sunkun ati la tururu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore aje fun eleyii, ifa ni ebo ki re aje naa o le baa tete tee lowo ni ko ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Gbogbo ohun tenu n je Akuko adie kan Epo Eko Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju ori ologbo kan, odidi ataare kan, ewe eman, ewe awoyoyo, saworo pepe, ao jo papo, ao maa fi oti loo

Videos

Watch Oyeku Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Odi, Oyeku Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Iwori Odu.