Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oyeku Ogbe

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Òyèkù Ogbè Excerpt
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oyeku-ogbe
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Opa gila awo ni Opa gila awo ni n se Adifafun agbaagba mefa tinbakin sota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore isegun fun eleyii, pe awon agbaagba mefa kan wa ti won n ba eleyii sota, pe ki eleyii o rubo, ko si bo esu ko lee ba a segun won.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan Obi meji Epo Eko Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oyeku logbe labara Babalawo awonriwon Adifafun awonriwon Ti n be laarin awon ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore isegun fun eleyii, ifa ni eleyii yoo ni ota kan ni egbe ti yoo maa soro fun sugbon ki o so enu re pelu iru eni be, pe yoo segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji Eja meji Abo adie kan Alabahun kan Akuko adie kan Epo igo kan Eko meji Opolopo owo.
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyeku logbe labara Kasape kafijaro adifaje Ti n tikole orun bowale aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa fore aje fun eleyii, ifa pe eleyii yoo rire gbogbo nibi ijoko re ati lenu ise.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ekuru funfun Opolopo eyin, Ogede omini, Oyin ati Obi Meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa tiri Adifafun Orunmila Aje nje lo ti ko yale wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oju aje n pon eleyii, ifa ni ko lowo lowo, ifa ni ki eleyii o rubo, ko si fi oya bofa, ifa ni aje o ya ile re.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oya kan Obi meji Opolopo oti Epo Opolopo owo Eyele

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

1. Ao bu yangi esu die, ewe segun sete, ewe alupaida, oko ataare kan, ao lo po, ao fi sin gbere igba ati eyokan la ori eni ja

Videos

Watch Oyeku Ogbe teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Iwori, Oyeku Odi, Oyeku Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Ogbe Odu.