O
This Odu represents wisdom and the ability to see beyond the surface to understand deeper truths.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Itakun peele awo eba ona
Adifafun aake oun iroko
Nijo ti won jo n sota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eleyii n ba eni kan sota, pe eni naa juulo sugbon ebo ni ko ru, ko le baa segun eni naa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aake kan
Akuko adie kan
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Orooro adi
Adifafun adie okooko
Ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo fobinrin re, ki awon ota o mo baa pa a molowo, ki iyawo re naa o si ma ki oloku tabi alaare fun ojo merindinlogun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Igbin meji
Obi meje
Epo pupa
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Igijegede sogbade
Adifafun mansinwo
Tii somo itobi laafi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni keleyii o rubo lenu ise re pe yoo la ko si ma sinwo lenu ojo meta yoo nitori aje.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo obi
Eku emon meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Igijegede sogbade
Adifafun Aganronke
Ti n sawo relu okere
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ibi kan ni eleyii nlo pe korubo yoo sir ire bo nibe.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Epo
Eko
Agbado
Owo
Explore Ifa
Oyeku Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oyeku Ofun Odu.
