O
This Odu emphasizes the importance of balance and harmony.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Okanran funfun minni
Adifafun aje omo olopo oni
Omo abani tule aye eni se
Igba ti n ode orubo waye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa nip e oun pere aje pupo fun
eleyi ebo ni ki eleyi ose kole
bani aje lowo kio si lobo aje
pelu pepeye meji ati oyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Oyin
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Kanran kanran fun
Kanran kanran ofun
Adifafun duru
Ti n momi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire apesin fun eleyi ki eleyi orubo ki o le bari eni pe si kio lofi ori eye osi fi akuko kan rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ori eye osin
Agbon kan
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Monse Koran omo ipo
Adifafun duru eyin ti yio paja
Ojogbo je
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire asegbe fun
eleyi ki eleyi orubo pe gbogbo
oun ti bASE yio mon se ni ASEgbe
kio rubo pelu aja kan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aja kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Okanran ni kotile fun roke
Adifafun orisala osere mongbo
Igba ti lo oko aileron lodun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire gbogbo fun
eleyi lati okore ebo nikose
ki o si lobo orisale pelu
opolopo igbin ati eye etu kan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Opolopo igbin
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju itanna tanna powo
ao lo pelu iyere ao wa mu
eran monlu ao gesi mokanle
ni ogoji kekere ao wa seni
epo ni yo ao wa se
adurasi ao wa je obe naa
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju awo ilu duru ta bi
awo ilu ara ao lo ao po
mon ose dudu ao wa mon fiwe
larolaro
Explore Ifa
Okanran Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Okanran Ofun Odu.
