Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni ikoko odu abenu kuhukudu
Adifafun ose
Ti n lole se oyun inu re si obara lorun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa peki elelyi o mon se oyun inu re ti o ba se agidi iku ni ere ese
Ifa pe enikan ni ti nfi obe eyin je orere nisu tabi ki eni o je eni ti ojulo ninu agbara ifa pe ko jawo ninu nkan tin se ki o mon ba ku iku ojiji

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

agbebo adie
Eku
Eja
Akuko adie meji
Epo
Eko
Oruko kan fun esu
Akuko adie meji
Agbebo adie meji
Epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni danpara ni
Omun agbonrin lese
Adifafun ose oun Olobara
Won jo n sawo re ibi atoke doke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe awon omo iyameji kan niyi ti won nlosi ibikan tabi ore meji, ifape ki won orubo ki won o le mun ire bon be
Ifa pe ki elleyi o fi aso re ti oferan julo rubo nitori arun ti o yo kuro ninu egbe ki o mon di eni ti aye o mon safun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele merin
Pepeye meji
Eyeetu meji
Epo
Eko
Aso ara
Akuko adie meji
Eyele meji
Agbebo adie meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ela were ose
Nbe lowo olobara
Elawere olobara
Nbe lowo ose
Adifafun ose nsunkun
Pe oun ko ni owo lowo
Olobara nsunkan pe oun
Ko nire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa peki olomo iya meji ki won o fi inukonu ki won o le ba bo ninu iya ti nje won.
Ifa pe ki eleyi o mo ko oro si omo iyare lenu ifa pe omo ityare ni yio yo kuro ninu ewu buruku

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie merin
Agbebo adie merin
Eyele merin
Epo
Eko
Okete kan
Akuko adie meji
Pepeye meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni idunkudun oyo
Ifokifo ogbigbi
Adifafun agunyonmbo aja
Omo omo ni won ni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe ki elelyi o lo bo egbe orun re ni ounje ati oti pelu obi ntori omo
Ifa pe ogun kan nbe niwaju eleyi Ifa peki o lo bo sango ki o leba ni isegun nbe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewure kan
Aso funfun pupo
Eyele meji
Pepeye meji
Epo
Eko
Agbo ni sango gba
Akuko adire meta
Epo ati eko
Ota sango

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ibosi ewure ti won fib o egbe yen ewe abo ewe orijin ewe patanmon ao jo pelu odidi atare merin ao fi sin gbere si orikerike ara ao fi iyoku fo eko tutut mun ni araaro
ao te iyereosun ti afi da ifa yii ao te ni odu ifa (osebara) ao pe ifasi ASE isure si ao fi oti oyinbo lo.
ISEGUN
Epo apa epo ose iginla eeru Alamo ao gun papo mon ose dudu ao lo kanhun bilala yoi kun naa daa ao te ni odu ifa (ose kanran

Videos

Watch Ose Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Ose Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ose Obara Odu.