O
Read This Odu in Other Languages
Verse-level switching (Yoruba, English, Spanish, Portuguese, French) is available directly inside each verse below.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ose seranseran
Oni eni ti jewo fun
Adifafun ose ti o
Mon ji obinrin iolokanran fe
Oni eni ti jewo fun
Adifafun ose ti o
Mon ji obinrin iolokanran fe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire gbogbo fun eleyi
EBO ni ki elelyi ose io fi
eye etu meta rubo ki ire
ole ba tolowo
EBO ni ki elelyi ose io fi
eye etu meta rubo ki ire
ole ba tolowo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyeetu meta
Epo
Eko
Obi
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ose seran seran
Oleni ti jewo fun
Adifafun opolo
Tii se omo onibu iragbiji
Igbati won ni kogbe aso
Ara re rubo ntori arun
Eyi to feti otun gbebo
Ofi tosi danu
Nje kinni nle opolo lomi arun
Arun nile opolpo lomi arun
Oleni ti jewo fun
Adifafun opolo
Tii se omo onibu iragbiji
Igbati won ni kogbe aso
Ara re rubo ntori arun
Eyi to feti otun gbebo
Ofi tosi danu
Nje kinni nle opolo lomi arun
Arun nile opolpo lomi arun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire gbebo fun eleyi
ki elelyi orubo ki isu re letan
kaye ebo ni kose kio fi
eyele meje rubo
ki elelyi orubo ki isu re letan
kaye ebo ni kose kio fi
eyele meje rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meje
Epo
Eko
Obi
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni oro mi nwaju
Tese bere leyin
Adifafun olokanran
Tise egbon ose
Tese bere leyin
Adifafun olokanran
Tise egbon ose
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni ki eleyi orubo ise oun
uya pe eleyi sise gidingan ebo
ni kose odidi eran elede ni
yio fib o ifa ki ara ole bade
uya pe eleyi sise gidingan ebo
ni kose odidi eran elede ni
yio fib o ifa ki ara ole bade
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Odidi eran elede kan
Epo
Eko
Obi
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ose seran seran
Oni eni ti jewo fun
Adifafun olukoso laalu
Arabanbi afi igba ota segun
Igbati nbe laarin osiri
Ti nbe laarin ota
Oni eni ti jewo fun
Adifafun olukoso laalu
Arabanbi afi igba ota segun
Igbati nbe laarin osiri
Ti nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire omo fun
eleyi pe oju omo nip on ebo
ni kose kole baa di olomo kio
si lobo ifa pelu eku meji eja
meji abodie meji
eleyi pe oju omo nip on ebo
ni kose kole baa di olomo kio
si lobo ifa pelu eku meji eja
meji abodie meji
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eku meji
eja meji
abodie meji
epo
eko
obi
eja meji
abodie meji
epo
eko
obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju ewe oriji ao toju ewe tete abalaye ao wa lopo ao wa
fi se odidi eye etu kan lepo ni yo ao wa ta oti oyinbo die si lori ina ti abASE tio baji naa ao w a so kale ao wa ko si ori ifa ao wa se adura si ao was mon je ni ori ifa yin titi ti yio ti tan
fi se odidi eye etu kan lepo ni yo ao wa ta oti oyinbo die si lori ina ti abASE tio baji naa ao w a so kale ao wa ko si ori ifa ao wa se adura si ao was mon je ni ori ifa yin titi ti yio ti tan
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ase ati agbo ati ewe segun sete ao wa lo papo ao wa po mon ose dudu ao wa lofi po eru oju aro ao wa lofi we ori sodo ti banu san
Explore Ifa
Ose Okaran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Okaran Odu.
