Ò
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ikoko odu abenu kuhukudu
Adifafun ose
Ti n lole se oyun inu re si obara lorun
Ebo ni won ni ko se
Igba aitubo
Igba aiteru
Eyin ori ifa tawo ki
Biti nse
Ifa de alase ope abise wara
Ifa ni ose seranseran
Oni eni ti jewo fun
Adifafun ose ti o
Mon ji obinrin iolokanran fe
EBO ni won ni ko se
Igba aitubo
Igba aitu eru
Eyin ori ifa awo ki
Biti nse
Ifa de alase ope abise wara
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki elelyi o mon se oyun inu re ti o ba se agidi iku ni ere ese
Ifa pe enikan ni ti nfi obe eyin je orere nisu tabi ki eni o je eni ti ojulo ninu agbara ifa pe ko jawo ninu nkan tin se ki o mon ba ku iku ojiji
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
agbebo adie
Eku
Eja
Akuko adie meji
Epo
Eko
Oruko kan fun esu
Akuko adie meji
Agbebo adie meji
Epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni danpara ni
Omun agbonrin lese
Adifafun ose oun Olobara
Won jo n sawo re ibi atoke doke
Ebo ni won ki won o se
Won si gbebo nbe won rubo
Ero ipo
Ero ofa
Ewa bani bayi bola ba ire gbogbo
Ose seran seran
Oleni ti jewo fun
Adifafun opolo
Tii se omo onibu iragbiji
Igbati won ni kogbe aso
Ara re rubo ntori arun
Eyi to feti otun gbebo
Ofi tosi danu
Nje kinni nle opolo lomi arun
Arun nile opolpo lomi arun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe awon omo iyameji kan niyi ti won nlosi ibikan tabi ore meji, ifape ki won orubo ki won o le mun ire bon be
Ifa pe ki elleyi o fi aso re ti oferan julo rubo nitori arun ti o yo kuro ninu egbe ki o mon di eni ti aye o mon safun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele merin
Pepeye meji
Eyeetu meji
Epo
Eko
Aso ara
Akuko adie meji
Eyele meji
Agbebo adie meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ela were ose
Nbe lowo olobara
Elawere olobara
Nbe lowo ose
Adifafun ose nsunkun
Pe oun ko ni owo lowo
Olobara nsunkan pe oun
Ko nire gbogbo
Ebo ni won ni ki won o se
Won si gbebo nibe won rubo
Nje ose ngbegba ola
Olobara n gbe igba ire gbogbo
Ifa ni oro mi nwaju
Tese bere leyin
Adifafun olokanran
Tise egbon ose
EBO ni won ni kose
Osi gEBO nbe orubo
Nje kin ni o nije ogun o ja olokanran
Opelopo Ose
Ni onije kogun oja olokanran
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki olomo iya meji ki won o fi inukonu ki won o le ba bo ninu iya ti nje won.
Ifa pe ki eleyi o mo ko oro si omo iyare lenu ifa pe omo ityare ni yio yo kuro ninu ewu buruku
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie merin
Agbebo adie merin
Eyele merin
Epo
Eko
Okete kan
Akuko adie meji
Pepeye meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni idunkudun oyo
Ifokifo ogbigbi
Adifafun agunyonmbo aja
Omo omo ni won ni
Ebo omo ni won ni kose
O si gbebo nibe orubo
Nje awa o ni gunyan baja mon
Omo lawa o mon gunyan bo
Ifa ni ose seran seran
Oni eni ti jewo fun
Adifafun olukoso laalu
Arabanbi afi igba ota segun
Igbati nbe laarin osiri
Ti nbe laarin ota
EBO ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje kin ni arira fi sete
Igba ota larira fi sete
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pe ki elelyi o lo bo egbe orun re ni ounje ati oti pelu obi ntori omo
Ifa pe ogun kan nbe niwaju eleyi Ifa peki o lo bo sango ki o leba ni isegun nbe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewure kan
Aso funfun pupo
Eyele meji
Pepeye meji
Epo
Eko
Agbo ni sango gba
Akuko adire meta
Epo ati eko
Ota sango
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ibosi ewure ti won fib o egbe yen ewe abo ewe orijin ewe patanmon ao jo pelu odidi atare merin ao fi sin gbere si orikerike ara ao fi iyoku fo eko tutut mun ni araaro
ao te iyereosun ti afi da ifa yii ao te ni odu ifa (osebara) ao pe ifasi ASE isure si ao fi oti oyinbo lo.
ISEGUN
Epo apa epo ose iginla eeru Alamo ao gun papo mon ose dudu ao lo kanhun bilala yoi kun naa daa ao te ni odu ifa (ose kanran
Explore Ifa
Òsé Óbárà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Òsé Ogbè, Òsé Òyèkù, Òsé Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òsé Óbárà Odu.
