Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ó

Ósà Òsé

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Osa Ose
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the power of transformation and the need for adaptability in the face of change.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/osa-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Osa Ose

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Osa se Orin se Aase ti baba omo fi sile Loman un sole Adifa fun eegun Nin jo oun orisa jon sota Ebo wonin won ose Eegun nin kan nin be leyin tin tubo Ero ipo Ero ofa Ebanin laru segun Safun min un fun o eekan nin ofibi booroboro wole adifa fun alagbede okankan igba ti nbe laarin ota ebo wonin ose osirubo keepe keejinan ewa banin laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ota kan ree fun eleyi korudo yiosegun re sugbon ki eleyi onin suuru O koman kanju yio segun Keleyi orubo awon ota nin lara yio segun won.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eko Olele, Obi Orogbo Ataare, Oti bo eegun Epo, Eko, Agbado Owo. Epo Eko Agbado Akuko die kan Owo.
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Osa se Orin se Aase ti baba omo fi sile ninun sole adifa fun oro tinbe laarin ota ebo wonin ose osirubo eropo ero ofa ebanin laru segun Safun min Un ofun o eekan nin oti bi boro boro wole Adifa fun oosa nla osere mangbo Nijo tin sawo relu igodo Ebo ota ni won ni o se Osi gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Ebanin laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nin re isegun fun eleyi ebon in komanru Keleyi orubo ibikan nin loyi awon ota nin koninde ebon in kose yio lore yio bo re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aofi ogiri bo oro ewa ososo, obi ati oti Aofi epo, eko, agbado ati owo rubo Epo Eko Agbado Owo.
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Agbe tin bo Ara sosin owo enin apamun sanra adi faje olokun eyi tio lalala tenin kan onin le tenin fun man ebo wonin ose osirubo keepe keejinan an banin bola ba peregede Osa funfun sese Baba lawo aje Lodifa fun aje Ajen tode orun bowaye Ebo wonin ose O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Ebanin bola ba peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo eleyi ola ti enin kan onin ridi owo re Ifa pere fun eleyii, pe keleyi orubo, pe ire aje renrubo lai pe, pe ebo ni koru yoo nire gbogbo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Eyele meji funfun Agbado Owo. Epo Eko Agbado Eyele funfun meji Owo.
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Panbe lawe Panbe lawe Adifa fe fegun tin sawo rebi atoke doke ebo wonin ose osirubo keepe keejinan ajewajede tuturu Osafun yinyin Adifa fun orunmila Baba ji baba orowo kan ayo nan ebo wonin ose osirubo Nje igba lonin keeman gbayinwa Oori lonin eman rin yin bo Kin lonin won ope wa lawo yeepe lonin won ope wa lawo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nin re aje nbo feleyi eegun nin kolobo Keyi orubo Ko man kan ju o ire re fee detan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ao fi eko, olele, akara, obi, ati oti ao fib o eegun Ao fi epo, eko, agbado, owo ao fi rubo Epo Eko Agbado Owo.

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe igba Ewe oori Ewe yeepe Ao gun gbogbo re po man ose Ao man fi we

Videos

Watch Ósà Òsé teachings on our channel.

Explore Ifa

Ósà Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Osa Ose. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Osa Meji, Ósà Ogbè, Ósà Òyèkù, Ósà Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ósà Òsé Odu.