Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Orin se
Aase ti baba omo fi sile
Loman un sole
Adifa fun eegun
Nin jo oun orisa jon sota
Safun min
un fun o
eekan nin ofibi booroboro wole
adifa fun alagbede okankan
igba ti nbe laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
korudo yiosegun re
sugbon ki eleyi onin suuru O
koman kanju yio segun
Keleyi orubo
awon ota nin lara
yio segun won.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Orogbo Ataare,
Oti bo eegun
Epo, Eko,
Agbado Owo.
Epo
Eko
Agbado
Akuko die kan
Owo.
Ese — Yoruba Verse
Orin se
Aase ti baba omo fi sile ninun sole adifa fun oro tinbe laarin ota ebo wonin ose osirubo
eropo ero ofa ebanin laru segun
Safun min
Un ofun o
eekan nin oti bi boro boro wole
Adifa fun oosa nla osere mangbo
Nijo tin sawo relu igodo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
fun eleyi
ebon in komanru
Keleyi orubo
ibikan nin loyi
awon ota nin koninde
ebon in kose yio lore
yio bo re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo.
Ese — Yoruba Verse
Ara sosin
owo enin
apamun sanra
adi faje olokun
eyi tio lalala tenin kan
onin le tenin fun man
Osa funfun sese
Baba lawo aje
Lodifa fun aje
Ajen tode orun bowaye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
eleyi ola
ti enin kan onin ridi owo re
Ifa pere fun eleyii, pe keleyi orubo, pe ire aje renrubo lai pe, pe ebo ni koru yoo nire gbogbo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Eyele meji funfun
Agbado
Owo.
Epo
Eko
Agbado
Eyele funfun meji
Owo.
Ese — Yoruba Verse
Panbe lawe
Adifa fe fegun
tin sawo rebi atoke doke
Osafun yinyin
Adifa fun orunmila
Baba ji baba orowo kan ayo nan
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
nbo feleyi
eegun nin kolobo
Keyi orubo
Ko man kan ju o
ire re fee detan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe oori
Ewe yeepe
Ao gun gbogbo re po man ose
Ao man fi we
Explore Ifa
Osa Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Ose. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Osa Meji, Osa Ogbe, Osa Oyeku, Osa Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Ose Odu.
