Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Sisa lominun Agbada Salurawon
Adifafun orunmila
Baba nbe larin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ajenbo feleyi,
Ibikan leleyii nlo pe yoo rire munbo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Opolopo Owo
Ese — Yoruba Verse
Kamun peki kafiko peki
Kafigi ajameji korawan
Peki peki peki
Adifa fun esu odara
Won deru kale
Won ni omangbe karode – orun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko die meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
Osalufogbejo
Aso ayaban tube
Ninpopo
Adifufun sekere
Tinsawo rode oyo
Ebowonin ose osirubo
Eropo
Ero efa
Ewa banin bola ba peregede
Ese — Yoruba Verse
Erukun nso lalala
Adifafun orunmila
Iregbogbonlo lode
Okankan oyalewa
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Lati okeere korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Owo
Eyele merin.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Aofi akara bo esu pelu obimeji epo pupa, ao wa rojo si akara yi ao lofi sori esu.
Explore Ifa
Osa Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Ogbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Osa Meji, Osa Oyeku, Osa Iwori, Osa Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Ogbe Odu.
