Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
O fin ihajoko
Adifa fun lagbanaa
Nijo ti lo le fara so fa lodo ogbe
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Obu yankan yankan loju opon
Adifa fun olokosa lalu lambi omo arigba ota segun
Igba ti n be lari ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
Orogbo
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun orunmila
Nijo ti lo le gbada lowo orisa
Ti yio fi yomon rele lowo eleye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abo adire kan
Ada kan
Eku
Eja
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Mo meyin mi siwon ni se ku pa awon agbalagba isegun
E ri le mi bawon yii, omode wonyii koje n sinmi
Adifa fun orunmila
Won ni odun yin ni odun ola baba
Pe ebo ni won ni ko se
O gbebo nibe orubo
Ero ipo
Ero ofa
E wa bami ni jebutu ire gbogbo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Obi
Oti
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Osa Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Osameji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Osa Ogbe, Osa Oyeku, Osa Iwori, Osa Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Meji Odu.
