O
Ósà Méjì nínú Ifa Divination jẹ́ ká mọ ohun ìyanu tí kò ṣeé fojú rí, àwọn agbára tó fara sin àti agbára àyípadà.
Fetí sí mi
Odu Ifa Àpẹẹrẹ Ìfọkànsìn Mímọ́
Àwọn orúkọ oyè: Osameji
Àwọn àmì Odu mímọ́ tí wọ́n gbé sára àwo ìsọfúnni tó ń jẹ́ Ópele tàbí Ikin
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese Yoruba Ẹsẹ
Poko ni konidi O fin ihajoko Adifa fun laggbanaa Nijo ti lo le far so fa lodo ogbe
✦
Ase Ifa Ìsọfúnni Tẹ̀mí (Yoruba)
Ifa ni ire ola fun eleyin pe ki eleyin oni aforiti lodo eni ti baba sise daradara kio sib o orire peluojúÈrò inú máa ń dùn gan-an.
Ebo Ìrúbọ (Yoruba)
ojúFunfun meji Akuko adire kan Epo Eko Obi
Ètò àtúnṣe
Ese Keji
Ese Keji
Ese Yoruba Ẹsẹ
Osa meji lako ija Obu yankan yankan loju opon Adifa fun olokosa lalu lambi omo arigba ota segun igba ti n be lari ota
✦
Ase Ifa Ìsọfúnni Tẹ̀mí (Yoruba)
Ebo Ìrúbọ (Yoruba)
Eran oruko kan Akuko adire kan Epo Eko Obi Orogbo
3 Ètò ààbò
Ese Keta
Ese Keta
Ese Yoruba Ẹsẹ
✦
Ase Ifa Ìsọfúnni Tẹ̀mí (Yoruba)
Ifa ni ki eleyin orubo isegun kio si lobo orisa pelu eye etu ati ata kan sidi oriisa kio se bofa pelu abo adire kan eku eja.
Ebo Ìrúbọ (Yoruba)
Eye etu kan Abo adire kan Ada kan Eku Eja Epo Eko Obi
4 Ìwọ̀n
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese Yoruba Ẹsẹ
Momojumisiwon ni n seku pa baba lawo Mo meyin mi siwon ni se kupa awon agbalagba isegun E ri le mi bawon yii, omode wonyii koji n sinmi Adifa funorunmilaWon ni odun yin ni odun ola baba Pe ebo ni won ni ko se O gbebo nibe orubo Ero ipo ero Of E wa bami ni jebutu ire gbogbo
✦
Ase Ifa Ìsọfúnni Tẹ̀mí (Yoruba)
tó bá jẹ́ pé gbogbo èèyàn ló ń gbádùn ara wọn, kí ni mo lè ṣe fún ẹ̀mí mi?
Ebo Ìrúbọ (Yoruba)
Eran ewure kan Epo Eko Obi Oti
Awure Alchemist Formula
Èdè Yorùbá
Ao mun eran ewure ao ge si merindinlogun ao wa mun ewe aje ewe ire ewe peregun ewe ominnin o wa fi se won ewure yin ni eni naa ni yoo wo je ISEGUN
Isegun / Akose Ọ̀nà Ìṣẹ́gun
Èdè Yorùbá
ao mu akara elepo die ao mu ewe odunodun ewe tete ewe alo oko egun ori ewure ti won ba fib o ifa ao wa gun gbogbo re papao ao wa po mo ose dudu ao ma fi a laro laro
Àwọn fídíò
Wo ohun tí Osa Meji ń kọ́ni lórí ìkànnì wa.
Ṣàyẹ̀wò Ifa
Àwọn Àlàyé àti Ẹ̀rí
Jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tó máa sọ ohun kan nípa Osa Meji Odu.
