Ò
This Odu signifies the strength of character and the wisdom to navigate challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Koko eku nio tororo kanle
Adifafun orunmila
Baba o fi ojo ose saya
Ebo won ni o se osi gbebo nibe orubo
Nje, kini mose timo finiaje
Ose ni mose
Kin ni mose timo fi ni aya
Ose ni mo se
Kin mose timo fibimo
Ose ni mose
Kin mose timo fini ire gbogbo
Ose ni mose
OGBE SA
Okiti pete awo asagande
Adifafun asagande
Tin mo mi oju so gbere aje
Ebo won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Nje asagande ifa o gbo o
Emi rotitan emi o rowo san
Asagande ifa ogbo.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ki elelyi orubo ni tori aje kosi ma se ose fun ifa dada ki I re aje ole ba defun
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ko rubo ifa ni oju ajo pon ifa ni ko fi oti bo fa ko si gba oti naa lawinni ko gbodo fi owo lara leyin toba bofa tan ni kolo san owo naa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eyele opolopo owo
Eyele
Opolopo owo
Oti fun ifa
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ibinu ose kan fun ni
Suru ni baba iwa agba toni suru
Ohun gbogbo loni ajogbo ajato
Ajaayefa gbindingbindin bi eni tin la oyin
Adifafun orunmila
Baba n sawo lo sode iwo
Ebo won ni ose
Osi gbeo nibe orubo
Nje iya kan iyaakan ti babajebo niwo
Ni won npe niyawo.
Patako efan abi eda gbeke
Adifafun agbonrin galaja
Tise omo olugbo
Igba tin raye alaiku
Ebo wonni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje nisoju ekun oun ode
Agbonringala ja lawo kokumo
Nisoju ekun oun ode.
Fawo wale
Faleke wale
Adifafun etiponola tise Omoalahoro
Igba iwase
Igba tin momi oju sogbere ire
Ebo won ni kose
Os si gbebo nibe orubo
Nje etiponola de alahoro igba wase
Etiponla lo ahoro babare.
Ogbe tomopon
Abiamo sun mosi
Abiamo sunmosi tidi ala
Adifafun ojogbojokun
Ti n sawo rele olokun aweroro
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje ojogbojo kun
Ti o ba de ile olokun awe roro
Koyanbo aje, koyanbo aya, koyanbo omo koyanbo ire gbogbo komun aiku ko fi pelue.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifape ire fun eni to da ifayi ifa ni koma ni suru pe ire nbo fun ko ma ma binu ko ma ko egin ifa ni to ba rin irnajo pe kolo sugbon gbogbo oun tobari nibe ko gbodo fise ibinu
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ifani korubo si enu isere ifa ni awonkan nso lenu isere bi won o se mun ifa ni ti babare banbe laye komo ki laro laro koto losi enu ise ti ko ba si babare lare laye kobo babare ifa ni ori baba ni oyoninu ogun omo araye.
Ifape ire fun eni toda ifa yi ki osi rubo ki ire ola bato lowo ki osi ma jinnna si oso babare tori ire wa fun nibe.
Ifa pe ire fun eni toda ifayi korubo ifani irinajo kan ni elleyi felo korubo ko le ba ko re bo nirinajo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele akuko opolopo owo
Akuko adie
Eyele
Opolopo owo
Eyele
Opolopo owo
Eyele akuko adie opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Arogbodo lefo eerowo ni ti tete
Adifafun onidere moja
Omo afi gbin sebo ogboo
Adifafun oni dere moja
Omo a figbin sebo omo
Igba tin momi oju sugbere ire
Ebo won ni kose
O si gbebo nibe o rubo
Nje, Orunmila lo tan aye mi o le mo
Erowo lokun
Eroniomo je mowa domo ogbe yonu.
Ogbe sasa
Adifafun peregun
Ti omo araye omoro laro pin
Ebo won ni ko se
Ruru ebo
Eru atuka esu
Ewa bani laru se ogun
Omodin nio mofeda
Atanpako nio molete
Eyigunju won nikan nibe leyin tin topon se
Adifafun enlojo igi oko
Won raye alaniku
Ebo won ni ki won o se
Won gbebo nibe won rubo
Nje, apa nwowe iroko nwowe
Ati wowe agbon soro
Apa nwowe iroko nwowe
Ati wowe okun o soro
Apa nwowe iroko wowe ati wowe ope o soro.
Ogbetomopon
Abiamo sunmosi tidi ala
Adifafun yanmoti
Tin loko ailero lodun
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje bagbon yanmoti
Isin lamun omo mo
Maso omun bante omun sokoto.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ki elleyi o rubo ifa pe oun pe ire aiku fun oun si pere omo ko figbin ku eboru
Ika pe ire fun eni toda ogbe sa ifa ni ki orubo peawon omo araye nro laropin
Ifa pe ire fun eni toda ogbeka ki elelyi orubo ifa ni ounpe ire aiku fun ifa ni ko ni bawon kuku owowo
Ifa pe ire fun enmi toda ifayi ifa pe ire omo fun ko sibofa ni ije imun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin
Akuko
Opolopo owo
Akuko adie
Opolopo owo
Oruko kan
Akuko
Opolopo owo
Eku eja aboadie opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kukuduku pete nana ki eerin kan
Agbado agbodo egberin sepeteri
Adifafun elelgunmojo
Omo olowo eyo
Igba ti n momi oju sogbe ire
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Nje eegun lowo eegun yafa
Eyin o mo powo mini legun nlo
See wele,
Se wele
Adifafun gbogbo okookanle nirunmole
Won gbogun lo
Ilubinrin won lo ni bee niwon riwon mu
Adifafun orunmila baba wo ogun ilubinrin
Ebo wonni ki won o se
Orunmila ni kan ni be leyin tin sebo
Nje sewele sewelwe are ledu wa se
Ko moja ounle wa gba eku
Oje olukan wa gba eja
Oje olu oro wagba eye
Oje sewele sewele
Are leduwase komoja
Ogbe karele omo osin
Ogbe ka rele omo ora
Ogba karele omo ogun lele alede
Adifafun aje tin torun bowaye
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe orubo
Nje owindin mi owindi
Ire aje wajede tuturu.
Ogbe tomopon
Abiamo sunmosi
Abiamo abisunmosi jangele jangele
Adifafun obi tin sunkun omolo si okiti efan
Ebo won ni ose
Osi gbebo nibe orubo
Kepe
Kejina
E wa bani nije butu omo
Opejebutu omo lawa wa.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni to da ifayi ki elleyi o rubo nitori ola ifa ni ounpe ireaje fun leleyi korubo kire aje ole bade fun
Ifa pere fun eleyii, pe ebo ni ko o ru yoo sila ti yoo lu lenu ise re, sugbon ki o ma ni okanjua.
Ifa pe ire fun eni toda agbeka korubo ni tori aje ki aje ola ba to loowo ko si ekuru funfun bo aje ko si rubo kole bani isinmi
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ifa ni oju omo upon elleyi korubo yo di olomo laye ko fi agbebo ad bo fa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Akuko adie
Opolopo owo
Eku
Eja
Eye
Akuko adie
Opolopo owo
Eyele
Ekuru funfun
Opolopo owo
Aboadie
Akuko
Opolopo owo
Oti
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe okika efun osun aojo po mo arawon ao ro sinu ato ao pa akuko kan si ao ro ejere si ao ma fi oti sinabu lo larolaro.
MEDICINE TRANSLATION
La hierba de okika, efun sustancia blanca en polvo, osun la sustancia roja en polvo se mezclará y se derramará en un guardia medicinal matará a un gallo y le arrojará toda la sangre y uno se la llevará con vino shinarp todas las mañanas.
Ewe oju oro osibata obere omi okun yanrin oku yanrin osa eru Alamo ao gun gbogbo re ponmo ose omi okun yi lao fipo ao kosinu ike funfun ao ma fiwe laro laro
Ewe rekureku ewe ogo ewe omini ao jo po ao ro si ibi kan ao ma fi oti lo larolaro.
Ewe ominsin minsin ita kun ao lomo iyere ao fi se eyin adire merin leponiyo ao fiyerosun te odure.
MEDICINE
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe emun, igi ti sangopa aojo po mo odidi atare kan ao fisin gbere kan si arin ori.
MEDICINE
Ewe imi eran eru Alamo ako okuta were mesan ao gunpo mo arawo ao wa pomo ose ao ko si ori okuta ako kan ao ma fiwe.
MEDICINE
Ewe idi, odidi atare kan ao jopo ao ma fi omitutu lo larolaro.
Tangiri odidi kan opolo aye kan ao jo po mo odidi atara kan ao ma fi fo eko tutu mnu laro laro.
MEDICINE
Explore Ifa
Ògundà Ogbè is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Meji, Ògundà Òyèkù, Ògundà Iwòrì, Ògundà Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ògundà Ogbè Odu.
