Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Ògundà Íká

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in navigating life's challenges.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ogunda-ika
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Aya silasila Aya silosilo Adifafun won ni Ilu ko sebo kosin oosa Ibi ti won ti npese sile De ogun Won ni won o karasiri Ebo ni won o se Won sigbebo nbe wonrubo Nje togun langbo Togun lase Togun wa loju ona

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe eni ti o da ifa yi ki orubo kosi boo gun dada nitori ogun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan Alabahun Akuko Epo Ewa Oti Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ika gunda awo olonko Adifafun olonko Omo aribon seye iyawo Ebo ni won ni kose Osi gbebo nbe orubo Nje iyawo legbe leyinbon Ikagunda o ara da nbe

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o bogun ti oba fe se etutu re leyin na ki won o si yinbon leyin etutu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Eyele meji Agbebo adie meji Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ika mida Ika mi run Ika mi o mirun Sunhin sunhin Adifafun orunmila Ifa nbe nirogun ota Ebo ni won nifa ose Osi gbebo nbe o rubo Ero opo ero ota Ebawa laruse ogun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o rubo isegun ota ifa pe aarin ota ni eleyi wa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan Akuko adie meji Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ika mida Ika mirun Ika mi o mirun Sunhin sunhin Adifafun esu odara Ntorun bo wale aye Ebo ni won ni kose Osi gbebo nbe orubo Kee pe Kee jina Ebani ni jebutu ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ki eleyi orubo ifa ti o ba ti de awujo ko le mon ri ifa je

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji Eyeetu meji Akuko adie meji Epo Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

IRE-AJE Yepe idi esu ti n gbebo dada ewe won jo tutu ao gun papo mon ose dudu ako sinu paaka idi esu Ao te iyere osun ni IKAGUNDA ao po papo mon

Videos

Watch Ògundà Íká teachings on our channel.

Explore Ifa

Ògundà Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Meji, Ògundà Ogbè, Ògundà Òyèkù, Ògundà Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ògundà Íká Odu.