Ò
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in navigating life's challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Aya silasila
Aya silosilo
Adifafun won ni
Ilu ko sebo kosin oosa
Ibi ti won ti npese sile
De ogun
Won ni won o karasiri
Ebo ni won o se
Won sigbebo nbe wonrubo
Nje togun langbo
Togun lase
Togun wa loju ona
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe eni ti o da ifa yi ki orubo kosi boo gun dada nitori ogun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Alabahun
Akuko
Epo
Ewa
Oti
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ika gunda awo olonko Adifafun olonko Omo aribon seye iyawo Ebo ni won ni kose Osi gbebo nbe orubo Nje iyawo legbe leyinbon Ikagunda o ara da nbe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o bogun ti oba fe se etutu re leyin na ki won o si yinbon leyin etutu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Eyele meji
Agbebo adie meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ika mida
Ika mi run
Ika mi o mirun
Sunhin sunhin
Adifafun orunmila
Ifa nbe nirogun ota
Ebo ni won nifa ose
Osi gbebo nbe o rubo
Ero opo ero ota
Ebawa laruse ogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o rubo isegun ota ifa pe aarin ota ni eleyi wa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Akuko adie meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ika mida
Ika mirun
Ika mi o mirun
Sunhin sunhin
Adifafun esu odara
Ntorun bo wale aye
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Kee pe
Kee jina
Ebani ni jebutu ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ki eleyi orubo ifa ti o ba ti de awujo ko le mon ri ifa je
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Eyeetu meji
Akuko adie meji
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
IRE-AJE
Yepe idi esu ti n gbebo dada ewe won jo tutu ao gun papo mon ose dudu ako sinu paaka idi esu
Ao te iyere osun ni IKAGUNDA ao po papo mon
Explore Ifa
Ògundà Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Meji, Ògundà Ogbè, Ògundà Òyèkù, Ògundà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ògundà Íká Odu.
