Ò
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Eda o gbo ogun
Ebo ni ifa ni ka mon se
Adifafun ori
Nijo ti fi omi oju
Sogbere ire gbogbo
Ebo ni won ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Nje ire gbogbo
Esa re wa ba ori duro
Ori o ni ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon bo ori re dada ki o mon gbekele oogun nkan ki o si mon peese fun awon agbalagba dada kosi mon rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Akuko adie meji
Eyele meji
Okete
Ki ofi eye etu kan
Bo ori re pelu obi ati oti
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori aweda
Eda ogboogun
Ebo ni ifa ni ka mon se
Adifafun orunmila
Baba nfomi oju sogbere aya
Ebo ni won ni ko mon se
O si gbe bo nibe orubo
Nje ekowo wa ewa yan
Edu loko
Akuko gagara koni kowo
Se oko gbebo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire lati ipase obinrin fun eleyi, Ifa eleyii si nwa obinrin korubo daada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie meji
Eye etu meji
akuko kan
Obi
Oti
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori wo oun
Rere da
Iwori wo oun rere da
Ifa bi o bada rere tan
Ki o se rere ku fun mi
Adifafun orunmila
Baba nfomi oju sogbere aje
Ebo ni won ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Nje iwori worere da fun miwa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii rubo ire gbogbo ki ire ole to lowo ki osi rubo nipase omo iyare kan ti yio laa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Akuko adie meji
Eyeetu meji
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori okete meta ewe mon fowo ba omo mi pupo odidi atare meta ao jo papo
Ao pe ifa si ao mon fi fo eko tutu mun lalelale
Explore Ifa
Ògundà Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Meji, Ògundà Ogbè, Ògundà Òyèkù, Ògundà Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ògundà Iwòrì Odu.
