O
This Odu signifies the need for cleansing and renewal to overcome past difficulties.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Olowo nin foko
Olofa aferu
Iwooraala
Emi o raala
Aroko ma raala lodijale
Adifafun foyeku
Ti yoo pakin ose soko nitori ija ogede
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o ma ja sile oko tabi keleyii o sora fun orere pelu ija
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Elede kan
Ogede agbagba
Obi
Owo, Oti, epo
Eko, agbado ati owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Olowo nin foko
Olofa aferu
Iwooraala
Emi o raala
Aroko ma raala lodijale
Adifafun Bayarin ti n be loko iwofa Ebo ni won
ni ko se
O sigbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
E bani larusegun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo senu ise re, pe awon ota po feleyii lenu ise re, pe ebo ko le ba a segun ni ko ru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ojonla nin sewe koko rororiri ririroro adifafun oosa nla oseremagbo Ti n sunkun pe oun o foju bare
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo nitori pe ire aje n bo fun eleyii, ko sibo orisa nla oseremagbo kire aje naa o le baa je fun un.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin mejo
Obi meji
Oti
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ketekete abeeku poopoopo
Adifafun Omosun an abera owo
Eyi ti yoo firinwo sowo
Ti yoo jeer egbeje oke
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni keleyii o rubo senu ise re, pe yoo ri ola naa lenu ise ti oun se.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
Explore Ifa
Oyeku Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oyeku Ose Odu.
