O
Ogunda Meji in Ifa Divination symbolizes strength, courage, and the transformative power of persistence.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ogundaji awo ibon
Lo sefa fun ibon
Nigba ti nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire isegun fun eleyin be bo ni kose kio si lo fi eja abori meji boo gun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Eja abori meji
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ore lope
Ika kosunhan
Adifa fun ajanaa
Ni jo ti lole je oloko
Lai ba won tan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
If ape ire gbogbo fun eleyin ebo ni ko se ifasipe ire fun komo se ore daradara kio si fi eye etu kan bo ori re ki o fi akuko kan rubo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Akuko adie kan
Epo
Obi
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Abemonle ekan
Abojuregunregun
Adifa fun oori ti n sunkun omo rode ipo
Odi fa fun oori ti sunkun omo rode ofa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ohun pe ire omo fun eleyin pe oju omo nip on eleyin ebo ni ko se kio si lobo orisa pelu igbin merin.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin merin
Eku kan
Eja kan
Abo adire kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Orekojonaa sefinrin
Adifa fun orunmila
Nijo ti lo le gba obinrin kan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ohun pe ire isegun fun eleyi , ki eleyi o ru bo, ki o si lo bo ifa pelu eran ewure
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
Ewe taba
Oti
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao mu obemonle ekan ati ewe osusu ao wa gun mon ose dudu eni naa yio wa maa fi we larolaro.
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ewe taba ao gun po mon ose ao wa fi oti oyinbo po ao wa tun fi ewe taba die ao wa tun da sinu oti oa mon mu oti yii ao si mon fi ose we.
Explore Ifa
Ogunda Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Ogbe, Ogunda Oyeku, Ogunda Iwori, Ogunda Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Meji Odu.
