Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ose Oyeku

Ose Oyeku also known as Ose Yeku
Aliases: Ose Yeku
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ose-oyeku
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ose Yeku

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni akuko pa Oagunmon ese Adifafun akinyode Ti se omo olose yeku Igbati nfomi oju sugbere ire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o mon se biti ifa daada ifa ni yio gba ire re fun nibikibi tore re wa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele funfun meji Akuko adie meji Pepeye kan Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni ara iwaju oba Ero eyin la duro de Adifafun orunmila Iku npa egbe re ni Rogbarogba ni rewerewe Bi eni to ji min iku je Won ni ki baba ogbebo korubo Osi gbebo nbe orubo Ero ipo Ero ofa Eba ni laiku kagiri gidi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elelyi o mon kanju ju eleda re, ki osi mon toripe awon kan ti wa niwaju ki o wa sope oun fe lewon ba, Iku nbe nibe fun un.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Alabahun meji Igbin mejo Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Akuko pa ogan mon ese Adifafun odun nbaku Ti se omo aja niwarun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo nitori iku ki o ni adie alawo meta akuko adie pe yoo rire gba

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan Akuko adie alawo meta Igbin merin Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni roto roto Eyin amun Adifafun ifaronke Omo elegba odundun Igbati nsogbogbo arun Ti n nara kaka Ai le dide

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa omo kan ni ti nfonku fola dide, ifa pe ki won o mon oko re iyawo ifani toba je okubnrin ni ki o lo tefa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meji Akuko adie meji Eyele meji

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AJE Yio ni omi esun ti o basun Ao fi gbo ewe awoyoyo pelu Ewe eti ponola Ao te iyere osun ni (oseyeku) ASE isure si dada ao toro nkan ti Abafe si ao mon fi won le Gbogbo ibi ti aba wa.

Videos

Watch Ose Oyeku teachings on our channel.

Explore Ifa

Ose Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ose Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Iwori, Ose Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ose Oyeku Odu.