Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Oagunmon ese
Adifafun akinyode
Ti se omo olose yeku
Igbati nfomi oju sugbere ire
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Pepeye kan
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Ero eyin la duro de
Adifafun orunmila
Iku npa egbe re ni
Rogbarogba ni rewerewe
Bi eni to ji min iku je
Won ni ki baba ogbebo korubo
Osi gbebo nbe orubo
Ero ipo
Ero ofa
Eba ni laiku kagiri gidi
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin mejo
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Adifafun odun nbaku
Ti se omo aja niwarun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie alawo meta
Igbin merin
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Eyin amun
Adifafun ifaronke
Omo elegba odundun
Igbati nsogbogbo arun
Ti n nara kaka
Ai le dide
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eyele meji
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Yio ni omi esun ti o basun
Ao fi gbo ewe awoyoyo pelu
Ewe eti ponola
Ao te iyere osun ni (oseyeku)
ASE isure si dada ao toro nkan ti
Abafe si ao mon fi won le
Gbogbo ibi ti aba wa.
Explore Ifa
Ose Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ose Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Iwori, Ose Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Oyeku Odu.
