Ò
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Owonrin wese wese
Adifafun Orore
Ti n be laarin ota
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje orore o lee ja
Oko le tagbon
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo pe laarin ota ni o wa, paa paa enin o munle ti eleyii, ota eleyii ni ko sora fun un
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie kan
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Anin otonan
O n tonagbe
Adifafun Awonrinwon
Ti n je laarin ota
Ebo ni won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, Awonriwon momo de
Awo oko kii kere ni mo kere
Ti mo ti segun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo ota, pe ota po fun eleyii ti won si juulo, pe yoo segun won.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko
Asa meji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Owonrin wese
Adifafun orore
Ti n tode orun bowaye
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, mo reni ola selebo
Orunmila loweri ola feebo more nin
Ola selebo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyii o rubo, pe yoo la, ola naa yoo po titi po lopolopo, sugbon ebo ni ko se
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abodie meji
Igbin meji
Epo
Eko
Agbado
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Owonrin wese wese
Emi naa wese
Adifafun Orunmila
Ifa n lo lee weri ola feebo
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, mo reni ola selebo
Orunmila loweri ola feebo meronin
Ola selebo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyii o rubo ire, pe ire n bo fun un lati okere pe ebo ni ko maa ru ki ire naa o le tet tee lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin meji
Abodie meji
Eyele meji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
Explore Ifa
Òsé Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Òsé Ogbè, Òsé Òyèkù, Òsé Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òsé Òwónrìn Odu.
