Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifafun oloyo
To fi orile
Ti nbo ado
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
o mon gbokan le
oogun ki o mon se
etutu dada ki o si mon
bori re dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
kofi akuko adie meji
kofi agbebo adie meji
eku ati eja
epo ati eko
Ese — Yoruba Verse
Akasu banba ni won fi se oogun re
Adifafun teyin gbiwa
Tin lo ree sanwo onipin lorun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
isinmin lori gbogbo nkan
tin se wahala le lori if ape
etutu ni o gba kale
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Eye etu meji
Epo ati eko
Ese — Yoruba Verse
Adifafun gbogbo okanra irunmonle
Won ngbe EBO lo ode orun
Ajikanse lekun
Adifafun akilolo
Akilolo ngbe ebo lo ode orun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
o mon gi EBO se
alo rara ki o tete
mon rubo ti won
ba ti sofun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Akuko adie meji
Ese — Yoruba Verse
Alagemo ni oto sele
Oto gele beni koto we sori
Adifafun awurela
Ti n sawo losi ode ijebu
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
si ibi ti elelyi nlo ki o
le ba di eni ti won o mon
sare ra oja re ki oja re
mon ba kuta rara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eyeetu meji
agbebo adie meji
okete kan
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju ewe odundun ao te
iyereosun ni odu ifa (ose tua)
Ao da iyere osun si ara ewe odundun yi ao soro soke nibi ti ategun oti mon fesi
Explore Ifa
Ose Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ose Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Otura Odu.
