Ò
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ose funfun
Bi igba aje
Ore dodo bi agbon eyin
Adifafun aje
Aje ntorun bow a saye
EBO ni won ni ko se
Osi gbebo nbe orubo
Ero opo ero ofa
Kosi irunmonle bi aje mon
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe eni ti oda ifa yi
Ki olobo aje dada ki aje
Ole fi ile re se ibu joko
Ki osi mon binu pupo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ekuru funfun
Eyele funfun meta
Akuko adie meta
Eyeetu meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ose funfun bu igba
Ore dodo bi agbon eyin
Adifafun oluwo omo odo oba
Olomo atode orun gbe
Igba aje kari waye
EBO ni won ki ose
Osi gbebo nbe orubo
Ero opo
Ero ofa
Eba ni bola ba ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire aje fun
Eleyii, ifa lati ode orun
Ni eleda eleyi ti so pe
Yio la nile aye pe
Gbogbo arare ola ni
Ki omo se etutu ki osi
Mon bo aje pelu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyeetu meji
Agbebo adie meji
Akuko adie meji
Eyin ope
Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Okose oko fun
Ada se ada fun
Funfun ni ooni nsu
Ni ale odo
Adifafun oni wa kawa
Tise omo onibu iragbiji
EBO ni won ni ko se
O si gbebo nbe orubo
Nje tani ogbodo lowo oni
Oni wakawaka babare
Loni bu tabi ogbodo lowo oni
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ki eleyi
Omunra dada
Ifa pe won fe le ni
Ori eto re won fi eto
Re dun ki orubo sibe dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abefele
Akuko adie
Eran alagba
Ati eran oni
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Sefunsefun ni won
Hun ase riwon riwon
Ni won gbon ajo
Ihun ase bi eni gbon ajolo
Igbajo bi eni ti hun ASE
Igbin ni opa piri wofin
Awo ile ifirandan
Nibiti won tin wo bale ile won tikutiku
EBO ni won ni ki won ose
Won si gEBO nbe won rubo
Ero opo ero ofa eba ni
Laiku kanhun gidi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki elelyi
Orubo ntori iku
Papajulo eni ti oje
Balele ninu ile yen
Ifa pe korubo ntori emi re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo igbin
Eran oruko kan
Agbebo adie meji
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ikarahun igbin igba alabahun
Ewe arojoku ewe rekureku
Odidi atare meta ao jo papo
Ao lo ti o kun na dada
Ao te ni o du ifa (ose ofun)
Explore Ifa
Òsé Òfún is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Òsé Ogbè, Òsé Òyèkù, Òsé Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òsé Òfún Odu.
