Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Oru ni agbalagba n dagbaku idi
Adifafun won ni idi kunrin
Abufun won ni idi binrin
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye funfun meji
Akuko adie meji
Eku
Eja
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Ilele wa ti ilele
Ni ole lo ori igi
Adifafun osan niware
Omo osankin abifun
Osan niware omo osanhin
Adifafun ojumole
Tii se omo bibi inu agbonniregun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Esun isu
Akuko adie meta
Atare meta
Epo
Eko
Ese — Yoruba Verse
Isan ni arewa ejo
Adifafun oosala oseremogbo
Tise ojise eledumare
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aso funfun
Akuko adie meji
Agbebo adie meji
Epo
Eko
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Oru ni agbalagba
Dagbaku idi
Adifafun orunmila
Nijo gogbo ajogun ka baba monle pitipiti Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe orubo
Nje oto gege ni gbayi
Owo mi te ewe abiri kolo nigbayi
gbogbo isinku orun e peyinda
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
agbebo adie meji
eku ati eja fun ifa
obi ati oti
epo ati eko
ewe abirikolo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ewe abirikolo
ewe alupaide
ewe swegun sete
odindi atare meta
ao jo papo ao le ti okunna dada
ao te ni odu ifa (osedi)
Explore Ifa
Ose Odi is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Osedi. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Odi Odu.
