Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ti o bam on ise je
Ko mon je onise
Bi osi mon ise ko mon
Je oluse
Opnise lo wumi o luse osuhan
Adifafun oosala osere mongbo
Yio ran eja ati akan nse
Nje ise ti aran lo je re
Ise aran eja ran akan
Akan nikan lojise rere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elelyi
O rubo lori eyan meji
Ti won jo nsise kan naa
Ki won orubo sibe dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meta
Eyele funfun meji
Pepeye meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni alanga jija
Adifafun esu odara
Ti ofise babara sile
Ti o mon lo sise oni se

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elleyi orubo ki osi mon fi liana babara sile lori gbogbo nkan ti ba nse

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko fun esu
Eyeetu meji
Pepeye meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Mo sapamon sapamon
Ori mi ko sapamon
Morin ni koko rin ni koko
Eleda mi orin ni koko
Adfifafun adaba susu
Ti nfomi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ki elelyi orubo nitori omo ki osi mon se aigboran si nkan ti won ba sofun ifa ni npa liana awon onbi re niyio ti di olomo laye

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meji
Eyele funfun meji
Akuko adie meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni ose wiri wiri
Babalawo ewiri
Adifafun ewiri
Ewiri nlo si agbde

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elelyi orubo lori ibi tin lo ki ole badi eni iyi nibe ki aye sile gbatie dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Awo ewiri
Akuko adie meta
Eyeetu meji
Eyele meta

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ori eyeetu ti abafi bori odidi atare kana o jo pelu yepe idi esu ao te ni odu ifa (osedi) aio so isure si dada ao fi sin gbere si aaarin ori de ipako ao po iyoku mon ose dudu ao fi lemeta ni ale ti aba fe sun

Videos

Watch Ose Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Ose Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ose Iwori Odu.