Ò
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
oseka orele alado
orinka oroke iyero
Ihorohoro aka ki ba aka ninu je
adifafun olofin
oji nijoojumo nko ominu ajogun
Ebo ni won ni ko se
osi gbebo nbe orubo
nje ori mi gbami
aya mi gba mi
moje ogun aye ogbemi lo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki elelyi
obo ori re
ati ayare
ki o le ba segun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eye etu meji
Alabahun meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ose pakaja
Orin pakaja
Adifafun orunmila
Baba nbe laarin ota
Ebo ni won ni ko se
Osi gbebo nbe orubo
Kepe
Kee jinna
E ba ni laruse ogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki elleyi
orubo isegun
Ifa peki omojuto
ifa dada ifa ni yio segun fun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewure kan fun ifa
Akuko adie meji
Eyele meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni idakisi ona
Ni re ejo leyin
Adifafun olomo
Iyameji ti won o
Mon se owo
Aroye
Ebo ni won ni ki won o se
Won si gbebo nibe won rubo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ife pe ki omo
iyami orubo lori
ise ti won nse
ki enikan o mon se
eru enikan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
pepeye meji
eyeetu meji
akuko adie meji
eyeele meji
epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
yepe idi esu obi idi osa
orogbo isi sango ao lo papo ao te ni odu ifa (ose ka)
Explore Ifa
Òsé Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Òsé Ogbè, Òsé Òyèkù, Òsé Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òsé Íká Odu.
