Ó
This Odu signifies the power of transformation and the importance of embracing change.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Gidigidi gbonbi ose
Adifafun elelyi aponsin
Nijo ti n lo bi oku ope
Ebo ni won ni kose
Osigbebio ni be orubo
Nje gidiigidi gbonbi ose
Ifa boba buru mapon
Leyin ire
ao toju eran otolo ao toju ewe aje ewe ire ewe
omini ao wa fi se eran
otolo yi lepo wi yo ao
w ate iyere osun ni
odun ifayi ao wa se adurasi ao wa je obe naa ni owuro aojo keji
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire isegun fun elelyi ki elelyi orubo isegun kolo bo ifa pelu eran ewure kan pelu ije imu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eran erure kan
epo
eko
obi
oti
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Yangin abori kugun
Adifafun otolo beleye
Nijo ti lole gbayin lari
Eranko
Ebon in won ni kose
Osigbebo ni be orubo
Nje ifa oto gege kigbayin
Nile baba mi
Gege bi otolo bleje se
Gbayin lari eran ko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire iyin fun lelyi
EBO ni ko se kio si lobo
orire pelu pepeye kio sifi akuko adire meji rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye kan
Akuko adire meji
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Orisa ika kotougbika
Aro gunwon lobe
Won a pon salo
Adifafun sedigelete
Ti se obinrin esu
Igba timomi ojusogbere ire
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo ni be orubo
Eropo
Ero ofa
Ewa bani ni jebutu ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa p oun pe ire gbogbo fun elleyi
EBO ni kose kio lobo esu pelu
eran oruko ati oti oyinbo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Oti oyinbo
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Tubu ni yanrin
Kere ni yangi
Adifafun otolo beleje
Ti se egbon ibaka
Igbati won be nirogun ota
Ebo ni won ni kiwon ose
Won gbebo ni be won rubo
Nje boba buru ototo beleye
Oto gege kogbawo kuro win ibi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire isegun fun elelyin ki elelyi olobo ifa pelu ewure kan
kio si fi akuko adire rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Akuko adire
Epo
Eko
Obi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju ewe ologun sese ao toju atare ati ori kanko ao wa jo meteta papo ao wa fi sigbere si arin ori mokanlelogun ni gbere naa.
Explore Ifa
Ósà Òtùrùpòn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Osa Meji, Ósà Ogbè, Ósà Òyèkù, Ósà Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ósà Òtùrùpòn Odu.
