Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun durowoju
Igba tin be laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Leleyiwa
Pe Korubo
Kole baa segun awon ota re.
Keleyi orubo
yio segun ota
awon ota eleyi
yio man sa kiri
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Obi merin
Agbado
Owo.
Epo
Eko
Agbado
Eeru oju aro
Omin gbigbonan
Owo.
Ese — Yoruba Verse
Orin kanran
Adifa fun eegun
abufun eeru
ebo wonin wonin won ose
eegun nin be leyin tin tub o
eropo ero ofa ebanin laru segun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ota nan obi ju
eleyi lo keleyi orubo
yio segun ota nan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo.
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun onin
Sango omo abule sowo
igba tin fomin oju sogbere ire
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
fun eleyi lopolopo
oun yio da ilu fun eleyi
Ifa pere aje fun eleyii, pe korubo pe ire ajebo n bo fun eleyii
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Abo adire kan
Agbado
Owo.
Epo
Eko
Agbado
Eyele meji
Owo.
Ese — Yoruba Verse
Babalawo aje lodifa fun Aje
Ajentoru bowa le aye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
ire aje fun eleyi
lenun ise re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Etu
Owo.
Epo
Eko
Agbado
Owo.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe ela
Iyere efo
Ao lopo ao fije
Eja abori kanje
Lepo nin
Explore Ifa
Osa Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Obara. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Osa Meji, Osa Ogbe, Osa Oyeku, Osa Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Obara Odu.
