Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ogunda Meji

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Ogunda Meji in Ifa Divination symbolizes strength, courage, and the transformative power of persistence.
Listen
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ogunda-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ogundaji awo ibon Lo sefa fun ibon Nigba ti nbe laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire isegun fun eleyin be bo ni kose kio si lo fi eja abori meji boo gun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Eja abori meji Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ore lope Ika kosunhan Adifa fun ajanaa Ni jo ti lole je oloko Lai ba won tan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

If ape ire gbogbo fun eleyin ebo ni ko se ifasipe ire fun komo se ore daradara kio si fi eye etu kan bo ori re ki o fi akuko kan rubo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Akuko adie kan Epo Obi Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Abemonle ekan Abojuregunregun Adifa fun oori ti n sunkun omo rode ipo Odi fa fun oori ti sunkun omo rode ofa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pe ire omo fun eleyin pe oju omo nip on eleyin ebo ni ko se kio si lobo orisa pelu igbin merin.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igbin merin Eku kan Eja kan Abo adire kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Orekojonaa sefinrin Adifa fun orunmila Nijo ti lo le gba obinrin kan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ohun pe ire isegun fun eleyi , ki eleyi o ru bo, ki o si lo bo ifa pelu eran ewure

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi Ewe taba Oti

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao mu obemonle ekan ati ewe osusu ao wa gun mon ose dudu eni naa yio wa maa fi we larolaro. ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe taba ao gun po mon ose ao wa fi oti oyinbo po ao wa tun fi ewe taba die ao wa tun da sinu oti oa mon mu oti yii ao si mon fi ose we.

Videos

Watch Ogunda Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Ogunda Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Ogbe, Ogunda Oyeku, Ogunda Iwori, Ogunda Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ogunda Meji Odu.