O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ose Yeku
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni akuko pa
Oagunmon ese
Adifafun akinyode
Ti se omo olose yeku
Igbati nfomi oju sugbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o mon se biti ifa daada ifa ni yio gba ire re fun nibikibi tore re wa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelefunfun meji
Akuko adie meji
Pepeye kan
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki elelyi o mon kanju ju eleda re, ki osi mon toripe awon kan ti wa niwaju ki o wa sope oun fe lewon ba, Iku nbe nibe fun un.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Alabahun meji
Igbin mejo
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Akuko pa ogan mon ese
Adifafun odun nbaku
Ti se omo aja niwarun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo nitori iku ki o ni adie alawo meta akuko adie pe yoo rire gba
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Akuko adie alawo meta
Igbin merin
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa omo kan ni ti nfonku fola dide, ifa pe ki won o mon oko re iyawo ifani toba je okubnrin ni ki o lo tefa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meji
Akuko adie mejiEyelemeji
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Yio ni omi esun ti o basun
Ao fi gbo ewe awoyoyo pelu
Ewe eti ponola
Ao te iyereosunni (oseyeku)
ASE isure si dada ao toro nkan ti
Abafe si ao mon fi won le
Gbogbo ibi ti aba wa.
Explore Ifa
Ose Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ose Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ose Meji,Ose Ogbe,Ose Iwori,Ose Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Oyeku Odu.
