Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òwónrìn Ogbè

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of adaptability and foresight in overcoming challenges.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/owonrin-ogbe
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Osemin masesan Adire damin loogun N o foleyin Adifafun alabahun toun Orunmila jo n sota Ebo ni won ni ko se Orunmila nikan lo gbebo nibe to rubo Ero ipo Ero ofa E bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eni yii pelu enikan jo n sowo po, pe ebo ni ko ru komani ota re ni ko fe ki eleyii o sorire, sugbon eleyii yoo sorire, ebo ni ki o se

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji Eja meji Abodie kan Akuko adie kan Epo Eko Agbado Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ibi lebelebe eti aso leema wa Adifafun yeepe Ti yoo gbara re ti yoo gbagi oko Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, igi ti yeepe ba dimo Igi ola loda Keeru keeru kan kotunri ke mo.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ke eleyii o rubo pe aarin ota ni eleyii wa, pe ko rubo oun yoo gba eleyii sile lowo awon ota re.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewe yeepe lopolopo Akuko adie kan Epo Eko Maíz Opolopo owo.
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Pabutu yeke Adifafun jesu Ti n tode orun bow aye Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe Nje, pabutu yeke Jesu forula jeka oyo Pabutu yeke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo pe yoo la ti okiki re yoo si kan kaa kiri gbogbo aye.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Amala ati obe ohunla Eku meji Eja meji Obi meji Oti Eyele meji Epo Eko ati Agbado Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Pabutu yeke okun kan leru Adifafun Aje Igba ti n tode orun bo wa sile aye Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ko e pe o Ko e jinna Aje wa jede tuturu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni aje n bo fun eleyii lenu ise re, pe eleyii yoo la ti gbogbo aye yoo si mo on.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igba olomori kan Akuko adie kan Epo Eko agbado Owo.

Videos

Watch Òwónrìn Ogbè teachings on our channel.

Explore Ifa

Òwónrìn Ogbè is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Òwónrìn Òyèkù, Òwónrìn Iwòrì, Òwónrìn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òwónrìn Ogbè Odu.