Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òwónrìn Iwòrì

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/owonrin-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Owonrin weere Owonrin were Adifafun Sango Ti won o ma ape ni were Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, were len pewe gbemi Beeni o si bunije

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa so pe ota eleyii po pupo, won si n so eleyii kiri sugbon ko rubo yoo segun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Owonrin weere Owonrin weere Adifafun Olukoso laalu Ti n be laarin ota Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, ki lariri fi sete Igba ota larira fi sete

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni laarin ota ni eleyii w ape korubo, ko sib o sango pe yoo ni segun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Amala ati obe gbegiri Orogbo Oti Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Owanrin lawo aseje Iwori lawo asejere Adifafun olomo aji faja sere Igba ti n fomi oju sogbere aje Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E bani bola peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire aje fun eleyii lopo lopo, pe ebo ni ko ru, ki ire ola naa o le baa tete tee lowo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Omo eja meji Epo Eko Agbado Owo VERSE THREE
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Owonrin weere Adifafun Orunmila Baba o sowo igila Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, kutu kutu aba baba laja ti n tagi Igba todirole dede A baba ti n je lori esin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ninu osi ni eleyii wa sugbon, korubo aje, pe ire aje yoo sunbo lai pe.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igi idana Eyele meji Epo Eko Agbado Owo

Videos

Watch Òwónrìn Iwòrì teachings on our channel.

Explore Ifa

Òwónrìn Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Òwónrìn Ogbè, Òwónrìn Òyèkù, Òwónrìn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òwónrìn Iwòrì Odu.