O
This Odu signifies the importance of patience and persistence.
Read This Odu in Other Languages
Verse-level switching (Yoruba, English, Spanish, Portuguese, French) is available directly inside each verse below.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Owonrin yanrete rete rete
Adifafun Aje
Ti n tode orun bowa sile aye
Adifafun Aje
Ti n tode orun bowa sile aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere aje fun eleyii, pe aje n bow a joko sile eleyii, pe ebo ni ko ru pe yoo nire aje.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Obi meji
Oti
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
Obi meji
Oti
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Mantala man eekan laawi
Adifafun Owonrin
Ti o yan rete laso
Adifafun Owonrin
Ti o yan rete laso
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eleyii, ifa ni ebo ni ki eleyii o ru, ki o le baa ri ire naa gba, pe aso kan nbe lorun eleyii ti o wow a dafa yii pe ki o ma wo ma, pe awon aye ti dawo te.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie kan
Ase eleyii to wo
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ase eleyii to wo
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Owonrin Yanrete Rete Rete
Adifafun aje
Ti n tode orun bow aye
Adifafun aje
Ti n tode orun bow aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa fore aje fun eleyii, ifa ni aje n bo fun un pe aje bo wa joko sile re pe ebo ni ko ru.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu
Obi meji
Oti
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
Obi meji
Oti
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Owonrin yanrete rete rete
Adifafun Orunmila
Baba ji
Baba o lowo kan aayona
Adifafun Orunmila
Baba ji
Baba o lowo kan aayona
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eleyii, pe ebo ni ko ru, ifa ni o n saroye pe oun ko lowo lowo, sugbon ebo ni ko ru, yoo di olowo repete.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abo die kan
Eyele meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
Eyele meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
Explore Ifa
Owonrin Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Irete Odu.
