Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Owonrin Iwori

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/owonrin-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Owonrin weere Owonrin were Adifafun Sango Ti won o ma ape ni were

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa so pe ota eleyii po pupo, won si n so eleyii kiri sugbon ko rubo yoo segun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Owonrin weere Owonrin weere Adifafun Olukoso laalu Ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni laarin ota ni eleyii w ape korubo, ko sib o sango pe yoo ni segun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Amala ati obe gbegiri Orogbo Oti Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Owanrin lawo aseje Iwori lawo asejere Adifafun olomo aji faja sere Igba ti n fomi oju sogbere aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire aje fun eleyii lopo lopo, pe ebo ni ko ru, ki ire ola naa o le baa tete tee lowo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Omo eja meji Epo Eko Agbado Owo VERSE THREE
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Owonrin weere Adifafun Orunmila Baba o sowo igila

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ninu osi ni eleyii wa sugbon, korubo aje, pe ire aje yoo sunbo lai pe.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igi idana Eyele meji Epo Eko Agbado Owo

Videos

Watch Owonrin Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Owonrin Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Owonrin Iwori Odu.