O
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Owonrin weere
Owonrin were
Adifafun Sango
Ti won o ma ape ni were
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa so pe ota eleyii po pupo, won si n so eleyii kiri sugbon ko rubo yoo segun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie kan
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Owonrin weere
Owonrin weere
Adifafun Olukoso laalu
Ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni laarin ota ni eleyii w ape korubo, ko sib o sango pe yoo ni segun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Amala ati obe gbegiri
Orogbo
Oti
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Owanrin lawo aseje
Iwori lawo asejere
Adifafun olomo aji faja sere
Igba ti n fomi oju sogbere aje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire aje fun eleyii lopo lopo, pe ebo ni ko ru, ki ire ola naa o le baa tete tee lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Omo eja meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
VERSE THREE
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Explore Ifa
Owonrin Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Iwori Odu.
