O
Owonrin Meji embodies the essence of change, teaching that flexibility and resilience are essential for overcoming obstacles.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Owon owo lana won minni
Owon omi lade sun omi
Owon ohunjelape ni yan
Adifa fun ohunyo won
Ti se omo oba leyo ajorin
Igbati momo oju sogbere ire aje surusu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
If ape ire aje fun eleyin pe oju aje nip on korubo kole ba laje lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Abodie
Akuko
Eyele
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Aragadagba osumonre
Osumonre na ara gadanugba
Adifa fun iroko gbo
Ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyin orubo isegun pe awon kan lo gbogun ti eleyin ebo ni ko se ko si mon lobo ifa dara dara.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Eku sahin
Eja sanhin
Adifa fun ope eleju
Nijo ti yoo mon rin taje taje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire gbogbo fun eleyin ki eleyi orubo ki o si mo lobo ifa dara daran kole ba lowo lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Abodie
Akuko
Eyele
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ileke iyun gidi ti won ti wo dara dara epo opoto ao wagon gbogbore won ose dudu eni naa yio maa fi we.
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
A o toju epo iroko ati ewe iroko ati egbo iroko ao wa jopo mon odidi atare kana o wa fi si gbere lari ja ao mon fi iyo kan foko mu.
Explore Ifa
Owonrin Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Iwori, Owonrin Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Meji Odu.
